Jẹnẹsisi 40:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rí i pé oríṣìíríṣìí oúnjẹ Farao ni ó wà ninu agbọ̀n tí ó wà ní òkè patapata, mo bá tún rí i tí àwọn ẹyẹ bẹ̀rẹ̀ sí jẹ àwọn oúnjẹ yìí ní orí mi.”

Jẹnẹsisi 40

Jẹnẹsisi 40:15-23