Jẹnẹsisi 39:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Iṣimaeli mú Josẹfu lọ sí Ijipti, wọ́n sì tà á fún Pọtifari ará Ijipti. Pọtifari yìí jẹ́ ọ̀kan ninu àwọn ìjòyè Farao, òun sì tún ni olórí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin ọba.

Jẹnẹsisi 39

Jẹnẹsisi 39:1-3