Jẹnẹsisi 39:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wà pẹlu Josẹfu, ninu ilé ọ̀gá rẹ̀, ará Ijipti, níbi tí ó ń gbé. Àwọn ohun tí ó ń ṣe sì ń yọrí sí rere.

Jẹnẹsisi 39

Jẹnẹsisi 39:1-11