Jẹnẹsisi 38:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Láìpẹ́ arakunrin rẹ̀ náà wálẹ̀, pẹlu òwú pupa tí wọ́n so mọ́ ọn lọ́wọ́, wọ́n bá sọ ọ́ ní Sera.

Jẹnẹsisi 38

Jẹnẹsisi 38:25-30