Jẹnẹsisi 38:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ọmọ náà ti fa ọwọ́ rẹ̀ pada, arakunrin rẹ̀ bá jáde. Agbẹ̀bí náà bá wí pé, “Ṣé bí o ti fẹ́ rìn nìyí, ó hàn lára rẹ.” Ó bá sọ orúkọ rẹ̀ ní Peresi.

Jẹnẹsisi 38

Jẹnẹsisi 38:22-30