Jẹnẹsisi 38:3-5 BIBELI MIMỌ (BM)

3. Ó lóyún, ó bí ọmọkunrin kan, Juda sọ ọmọ náà ní Eri.

4. Ó tún lóyún, ó bí ọmọkunrin keji, ó sọ ọ́ ní Onani.

5. Ó tún lóyún mìíràn, ó tún bí ọkunrin bákan náà, ó bá sọ ọmọ náà ní Ṣela. Ìlú Kẹsibu ni ó wà nígbà tí ó bí ọmọ náà.

Jẹnẹsisi 38