Jẹnẹsisi 38:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún lóyún mìíràn, ó tún bí ọkunrin bákan náà, ó bá sọ ọmọ náà ní Ṣela. Ìlú Kẹsibu ni ó wà nígbà tí ó bí ọmọ náà.

Jẹnẹsisi 38

Jẹnẹsisi 38:1-6