Jẹnẹsisi 37:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá fi ẹ̀wù aláràbarà náà ranṣẹ sí baba wọn, wọ́n ní, “Ohun tí a rí nìyí. Wò ó wò, bóyá ẹ̀wù ọmọ rẹ ni, tabi òun kọ́.”

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:31-36