Jẹnẹsisi 37:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu yẹ̀ ẹ́ wò, ó sì wí pé, “Ẹ̀wù ọmọ mi ni, ẹranko burúkú kan ti pa á, dájúdájú, ẹranko náà ti fa Josẹfu ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ.”

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:31-36