Jẹnẹsisi 37:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá mú ọmọ ewúrẹ́ kan ninu agbo, wọ́n pa á, wọ́n sì ti ẹ̀wù Josẹfu bọ inú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:30-34