Jẹnẹsisi 35:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun tún sọ fún un pé, “Èmi ni Ọlọrun Olodumare, máa bímọ lémọ, kí o sì pọ̀ sí i, ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè ati ọpọlọpọ ọba ni yóo ti ara rẹ jáde.

Jẹnẹsisi 35

Jẹnẹsisi 35:4-20