Jẹnẹsisi 35:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun wí fún un pé, “Jakọbu ni orúkọ rẹ, ṣugbọn wọn kò ní pè ọ́ ní Jakọbu mọ́, Israẹli ni orúkọ rẹ yóo máa jẹ́.” Bẹ́ẹ̀ ni Ọlọrun ṣe sọ ọ́ ní Israẹli.

Jẹnẹsisi 35

Jẹnẹsisi 35:1-18