Jẹnẹsisi 35:12 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fún ọ ní ilẹ̀ tí mo fún Abrahamu ati Isaaki, àwọn ọmọ rẹ ni yóo sì jogún rẹ̀.”

Jẹnẹsisi 35

Jẹnẹsisi 35:5-19