Jẹnẹsisi 33:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ti àwọn iranṣẹbinrin ati àwọn ọmọ wọn ṣáájú, Lea ati àwọn ọmọ rẹ̀ sì tẹ̀lé wọn, Rakẹli ati Josẹfu ni wọ́n wà lẹ́yìn patapata.

Jẹnẹsisi 33

Jẹnẹsisi 33:1-6