Jẹnẹsisi 33:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Jakọbu ti gbé ojú sókè, ó rí Esau tí ń bọ̀ pẹlu irinwo (400) ọkunrin. Ó bá pín àwọn ọmọ rẹ̀ fún Lea ati Rakẹli, ati àwọn iranṣẹbinrin mejeeji.

Jẹnẹsisi 33

Jẹnẹsisi 33:1-3