Jẹnẹsisi 32:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà bá dáhùn pé, “A kò ní pè ọ́ ní Jakọbu mọ́, Israẹli ni a óo máa pè ọ́, nítorí pé o ti bá Ọlọrun ati eniyan wọ ìjàkadì, o sì ti ṣẹgun.”

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:18-32