Jẹnẹsisi 32:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà bá bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Kí ni orúkọ rẹ?” Jakọbu dáhùn pé, “Jakọbu ni.”

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:24-31