Jẹnẹsisi 32:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu bá bẹ̀ ẹ́, ó ní, “Jọ̀wọ́, sọ orúkọ rẹ fún mi.” Ṣugbọn ó dá a lóhùn pé, “Èéṣe tí o fi ń bèèrè orúkọ mi?” Ó bá súre fún Jakọbu níbẹ̀.

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:19-32