Jẹnẹsisi 31:54 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu bá rúbọ lórí òkè náà, ó pe àwọn ìbátan rẹ̀ láti jẹun, wọ́n sì wà lórí òkè náà ní gbogbo òru ọjọ́ náà.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:53-55