Jẹnẹsisi 31:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun Abrahamu ati Ọlọrun Nahori, àní, Ọlọrun baba wọn ni onídàájọ́ láàrin wa.” Jakọbu náà bá búra ní orúkọ Ọlọrun tí Isaaki baba rẹ̀ ń sìn tìbẹ̀rùtìbẹ̀rù.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:47-55