Jẹnẹsisi 31:52 BIBELI MIMỌ (BM)

Òkítì yìí ati ọ̀wọ̀n yìí sì ni ẹ̀rí pẹlu pé n kò ní kọjá òkítì yìí láti wá gbógun tì ọ́, bẹ́ẹ̀ sì ni ìwọ náà kò ní kọjá òkítì ati ọ̀wọ̀n yìí láti wá gbógun tì mí.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:48-54