Jẹnẹsisi 31:55 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní òwúrọ̀ kutukutu ọjọ́ keji, Labani fi ẹnu ko àwọn ọmọbinrin rẹ̀ ati àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀ lẹ́nu láti dágbére fún wọn, ó súre fún wọn, ó sì pada sílé.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:49-55