Jẹnẹsisi 31:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Èéṣe tí o fi tàn mí jẹ, tí o yọ́ lọ láìsọ fún mi? Ṣebí ǹ bá fi ayọ̀, ati orin ati ìlù ati hapu sìn ọ́.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:20-31