Jẹnẹsisi 31:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Èéṣe tí o kò fún mi ní anfaani láti fi ẹnu ko àwọn ọmọ mi lẹ́nu kí n fi dágbére fún wọn? Ìwà òmùgọ̀ ni o hù yìí.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:23-30