Jẹnẹsisi 31:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Labani pe Jakọbu, ó ní, “Èéṣe tí o fi ṣe báyìí? O tàn mí jẹ, o sì kó àwọn ọmọbinrin mi sá bí ẹrú tí wọ́n kó lójú ogun.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:21-27