Jẹnẹsisi 31:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Labani lé Jakọbu bá níbi tí ó pàgọ́ rẹ̀ sí ní orí òkè náà, Labani ati àwọn ìbátan rẹ̀ sì pàgọ́ tiwọn sí agbègbè olókè Gileadi.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:24-32