Jẹnẹsisi 31:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ọlọrun sọ fún Labani ará Aramea lóru lójú àlá, ó ní, “Ṣọ́ra, má bá Jakọbu sọ ohunkohun, kì báà jẹ́ rere tabi buburu.”

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:22-29