Jẹnẹsisi 3:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà dáhùn, ó ní, “Obinrin tí o fi tì mí ni ó fún mi ninu èso igi náà, mo sì jẹ ẹ́.”

Jẹnẹsisi 3

Jẹnẹsisi 3:3-17