Jẹnẹsisi 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun bi obinrin náà pé, “Irú kí ni o dánwò yìí?” Obinrin náà dáhùn, ó ní, “Ejò ni ó tàn mí tí mo fi jẹ ẹ́.”

Jẹnẹsisi 3

Jẹnẹsisi 3:3-21