Jẹnẹsisi 3:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun bi í pé, “Ta ló sọ fún ọ pé ìhòòhò ni o wà? Àbí o ti jẹ ninu èso igi tí mo pàṣẹ fún ọ pé o kò gbọdọ̀ jẹ?”

Jẹnẹsisi 3

Jẹnẹsisi 3:6-17