Jẹnẹsisi 29:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu sọ pé, “Oòrùn ṣì wà lókè, kò tíì tó àkókò láti kó àwọn ẹran jọ sójú kan, ẹ tètè fún àwọn aguntan ní omi mu, kí ẹ sì dà wọ́n pada lọ jẹ koríko sí i.”

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:1-14