Jẹnẹsisi 29:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dá a lóhùn pé, “Kò ṣeéṣe, àfi bí gbogbo àwọn olùṣọ́-aguntan bá dé tán, tí a bá yí òkúta kúrò lórí kànga, nígbà náà ni a tó lè fún àwọn aguntan ní omi mu.”

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:1-9