Jẹnẹsisi 29:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún bi wọ́n pé, “Ṣé alaafia ni ó wà?” Wọ́n sì dá a lóhùn pé, “Alaafia ni, wò ó, Rakẹli, ọmọbinrin rẹ̀, ni ó ń da aguntan bọ̀ ní ọ̀kánkán yìí.”

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:1-16