Jẹnẹsisi 29:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu bá sin Labani fún ọdún meje nítorí Rakẹli, ó sì dàbí ọjọ́ mélòó kan lójú rẹ̀ nítorí ìfẹ́ tí ó ní sí Rakẹli.

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:17-25