Jẹnẹsisi 29:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, Jakọbu sọ fún Labani pé, “Fún mi ní aya mi, kí á lè ṣe igbeyawo, nítorí ọjọ́ ti pé.”

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:11-22