Jẹnẹsisi 29:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Labani bá dá a lóhùn pé, “Ó tẹ́ mi lọ́rùn láti fún ọ ju kí n fún ẹni ẹlẹ́ni lọ. Máa bá mi ṣiṣẹ́.”

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:15-23