Jẹnẹsisi 29:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu nífẹ̀ẹ́ Rakẹli, nítorí náà, ó sọ fún Labani pé, “N óo sìn ọ́ ní ọdún meje nítorí Rakẹli, ọmọ rẹ kékeré.”

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:15-26