Jẹnẹsisi 29:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ojú Lea kò fi bẹ́ẹ̀ fanimọ́ra, ṣugbọn Rakẹli jẹ́ arẹwà, ojú rẹ̀ sì fanimọ́ra.

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:7-24