Jẹnẹsisi 24:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Kíá, ó ti da omi tí ó kù ninu ìkòkò rẹ̀ sinu agbada tí ẹran fi ń mu omi, ó sáré pada lọ pọn sí i, títí tí gbogbo wọn fi mu omi káríkárí.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:14-21