Jẹnẹsisi 24:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà fọwọ́ lẹ́rán, ó ń wò pé bóyá lóòótọ́ ni OLUWA ti ṣe ọ̀nà òun ní rere ni tabi bẹ́ẹ̀ kọ́.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:19-22