Jẹnẹsisi 24:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Rebeka ti fún un ní omi tán, ó ní, “Jẹ́ kí n pọn omi fún àwọn ràkúnmí rẹ pẹlu, títí tí gbogbo wọn yóo fi mu omi tán”

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:17-29