Jẹnẹsisi 23:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ará Hiti tí wọ́n wà níbẹ̀ jẹ́rìí sí i pé ilẹ̀ náà di ti Abrahamu.

Jẹnẹsisi 23

Jẹnẹsisi 23:17-20