Jẹnẹsisi 23:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni ilẹ̀ Efuroni ní Makipela, tí ó wà ní apá ìhà ìlà oòrùn Mamure ṣe di ti Abrahamu, ati ihò tí ó wà ninu ilẹ̀ náà, ati gbogbo igi tí ó wà ninu rẹ̀ jákèjádò.

Jẹnẹsisi 23

Jẹnẹsisi 23:12-20