Jẹnẹsisi 23:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Abrahamu gbà bí Efuroni ti wí, ó bá wọn irinwo (400) ìwọ̀n ṣekeli fadaka tí Efuroni dárúkọ fún un lójú gbogbo wọn, ó lo ìwọ̀n tí àwọn oníṣòwò ìgbà náà ń lò.

Jẹnẹsisi 23

Jẹnẹsisi 23:10-20