Jẹnẹsisi 23:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Abrahamu lọ sin òkú Sara sinu ihò ilẹ̀ Makipela, tí ó wà ní ìhà ìlà oòrùn Mamure, ní agbègbè Heburoni ní ilẹ̀ Kenaani.

Jẹnẹsisi 23

Jẹnẹsisi 23:16-20