Jẹnẹsisi 19:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, Lọti jáde kúrò ní Soari, nítorí ẹ̀rù ń bà á láti máa gbé ibẹ̀, òun ati àwọn ọmọbinrin rẹ̀ mejeeji bá kó lọ sí orí òkè, wọ́n sì ń gbé inú ihò kan níbẹ̀.

Jẹnẹsisi 19

Jẹnẹsisi 19:20-37