Jẹnẹsisi 19:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, èyí ẹ̀gbọ́n wí fún àbúrò, ó ní, “Baba wa ń darúgbó lọ, kò sì sí ọkunrin kan tí yóo fẹ́ wa gẹ́gẹ́ bí ìṣe àwọn eniyan.

Jẹnẹsisi 19

Jẹnẹsisi 19:25-38