Jẹnẹsisi 17:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“N óo fìdí majẹmu mi múlẹ̀ láàrin èmi pẹlu rẹ, ati atọmọdọmọ rẹ. Majẹmu náà yóo wà títí ayérayé pé, èmi ni n óo máa jẹ́ Ọlọrun rẹ ati ti atọmọdọmọ rẹ.

Jẹnẹsisi 17

Jẹnẹsisi 17:2-15