Jẹnẹsisi 17:6 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo sọ àwọn ọmọ rẹ di pupọ, n óo sì sọ ọ́ di ọpọlọpọ orílẹ̀ èdè, ọpọlọpọ ọba ni yóo sì ti ara rẹ jáde.”

Jẹnẹsisi 17

Jẹnẹsisi 17:1-14