Jẹnẹsisi 17:8 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fún ọ ní gbogbo ilẹ̀ Kenaani, ilẹ̀ náà tí o ti jẹ́ àlejò yìí yóo di ìní rẹ títí ayérayé ati ti atọmọdọmọ rẹ, n óo sì máa jẹ́ Ọlọrun wọn!”

Jẹnẹsisi 17

Jẹnẹsisi 17:4-10